Native Bible

Genesis 35:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Àwọn ọmọ Rakeli: Josẹfu àti Benjamini.

Genesis 35:24 in English

Genesis 35:24 · Berean Standard Bible

The sons of Rachel were Joseph and Benjamin.

Context

22Nígbà tí Israẹli sì ń gbé ní ibẹ̀, Reubeni wọlé tọ Biliha, àlè baba rẹ̀ lọ, ó sì bá a lòpọ̀, Israẹli sì gbọ́ ọ̀rọ̀ náà. Jakọbu sì bí ọmọkùnrin méjìlá. 23Àwọn ọmọ Lea, Reubeni tí í ṣe àkọ́bí Jakọbu, Simeoni, Lefi, Juda, Isakari àti Sebuluni. 24Àwọn ọmọ Rakeli: Josẹfu àti Benjamini. 25Àwọn ọmọ Biliha ìránṣẹ́bìnrin Rakeli: Dani àti Naftali. 26Àwọn ọmọ Silipa ìránṣẹ́bìnrin Lea: Gadi àti Aṣeri. Àwọn wọ̀nyí ni ọmọ tí Jakọbu bí ní Padani-Aramu.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.