Native Bible

Genesis 19:38 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Èyí àbúrò náà sì bí ọmọkùnrin, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bene-Ami. Òun ni baba ńlá àwọn ará Ammoni lónìí. 19.24 tí ó túmọ̀ sí, òkúta iná

Genesis 19:38 in English

Genesis 19:38 · Berean Standard Bible

The younger daughter also gave birth to a son, and she named him Ben-ammi.* He is the father of the Ammonites of today.

Context

36Àwọn ọmọbìnrin Lọti méjèèjì sì lóyún fún baba wọn. 37Èyí ẹ̀gbọ́n sì bí ọmọkùnrin, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Moabu. Òun ni baba ńlá àwọn ará Moabu lónìí. 38Èyí àbúrò náà sì bí ọmọkùnrin, ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Bene-Ami. Òun ni baba ńlá àwọn ará Ammoni lónìí. 19.24 tí ó túmọ̀ sí, òkúta iná

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.