Esra 8:4
Ezra 8:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
nínú àwọn ọmọ Pahati-Moabu: Elihoenai ọmọ Serahiah àti àwọn igba ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;
Ezra 8:4 in English
Ezra 8:4 · Berean Standard Bible
from the descendants of Pahath-Moab, Eliehoenai son of Zerahiah, and with him 200 men;
Context
2nínú àwọn ọmọ Finehasi:
Gerṣomu;
nínú àwọn ọmọ Itamari:
Daniẹli;
nínú àwọn ọmọ Dafidi:
Hattusi, 3nínú àwọn ọmọ Ṣekaniah;
nínú àwọn ọmọ Paroṣi:
Sekariah, àti pé àádọ́jọ ọkùnrin fi orúkọ sílẹ̀ pẹ̀lú rẹ; 4nínú àwọn ọmọ Pahati-Moabu:
Elihoenai ọmọ Serahiah àti àwọn igba ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 5nínú àwọn ọmọ Sattu:
Ṣekaniah ọmọ Jahasieli àti àwọn ọ̀ọ́dúnrún (300) ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀; 6nínú àwọn ọmọ Adini:
Ebedi ọmọ Jonatani, àti àádọ́ta ọkùnrin pẹ̀lú rẹ̀;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.