Native Bible

Ezra 2:8 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Sattu jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rún ó lé márùn-ún (945)

Ezra 2:8 in English

Ezra 2:8 · Berean Standard Bible

the descendants of Zattu, 945;

Context

6Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ àwọn ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin lé méjìlá (2,812) 7Elamu jẹ́ àádọ́ta lé lẹ́gbẹ̀fà ó lé mẹ́rin (1,254) 8Sattu jẹ́ ọ̀tàdínlẹ́gbẹ̀rún ó lé márùn-ún (945) 9Sakkai jẹ́ òjìdínlẹ́gbẹ̀rin (760) 10Bani jẹ́ òjìlélẹ́gbẹ̀ta ó lé méjì (642)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.