Native Bible

Ezra 10:42 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣallumu, Amariah àti Josẹfu.

Ezra 10:42 in English

Ezra 10:42 · Berean Standard Bible

Shallum, Amariah, and Joseph.

Context

40Maknadebai, Sasai, Ṣarai, 41Asareeli, Ṣelemiah, Ṣemariah, 42Ṣallumu, Amariah àti Josẹfu. 43Nínú àwọn ìran Nebo: Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Sebina, Jaddai, Joẹli àti Benaiah. 44Gbogbo àwọn wọ̀nyí ló fẹ́ obìnrin àjèjì, àwọn mìíràn nínú wọn sì bi ọmọ ní ipasẹ̀ àwọn ìyàwó wọ̀nyí.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.