Esra 10:26
Ezra 10:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nínú ìran Elamu: Mattaniah, Sekariah, Jehieli, Abdi, Jerimoti àti Elijah.
Ezra 10:26 in English
Ezra 10:26 · Berean Standard Bible
From the descendants of Elam: Mattaniah, Zechariah, Jehiel, Abdi, Jeremoth, and Elijah.
Context
24Nínú àwọn akọrin:
Eliaṣibu.
Nínú àwọn aṣọ́nà:
Ṣallumu, Telemu àti Uri. 25Àti lára àwọn ọmọ Israẹli tókù.
Nínú ìran Paroṣi:
Ramiah, Issiah, Malkiah, Mijamini, Eleasari, Malkiah àti Benaiah. 26Nínú ìran Elamu:
Mattaniah, Sekariah, Jehieli, Abdi, Jerimoti àti Elijah. 27Nínú àwọn ìran Sattu:
Elioenai, Eliaṣibu, Mattaniah, Jerimoti, Sabadi àti Asisa. 28Nínú àwọn ìran Bebai:
Jehohanani, Hananiah, Sabbai àti Atlai.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.