Eksodu 6:26
Exodus 6:26 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Aaroni àti Mose yìí kan náà ni Olúwa sọ fún pé, “Ẹ kó àwọn ará Israẹli jáde kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti ní ìsọ̀rí ìsọ̀rí.”
Exodus 6:26 in English
Exodus 6:26 · Berean Standard Bible
It was this Aaron and Moses to whom the LORD said, “Bring the Israelites out of the land of Egypt by their divisions.”
Context
24Àwọn ọmọ Kora ni:
Asiri, Elkana àti Abiasafu.
Ìwọ̀nyí ni ìran Kora. 25Eleasari ọmọ Aaroni fẹ́ ọ̀kan lára àwọn ọmọbìnrin Putieli ní ìyàwó, ó sì bí Finehasi fún un.
Ìwọ̀nyí ni olórí àwọn Lefi ni ìdílé ìdílé. 26Aaroni àti Mose yìí kan náà ni Olúwa sọ fún pé, “Ẹ kó àwọn ará Israẹli jáde kúrò ni ilẹ̀ Ejibiti ní ìsọ̀rí ìsọ̀rí.” 27Àwọn ni ó bá Farao ọba Ejibiti sọ̀rọ̀ nípa kíkó àwọn ará Israẹli jáde kúrò ni Ejibiti, àní Mose àti Aaroni yìí kan náà ni. 28Nígbà tí Olúwa bá Mose sọ̀rọ̀ ni Ejibiti,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.