Efesu 4:1
Ephesians 4:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí náà, èmi òǹdè nínú Olúwa ń bẹ̀ yín pé kí ẹ̀yin máa gbé ìgbé ayé tí ó yẹ sí ìpè tí a pè yín sí.
Ephesians 4:1 in English
Ephesians 4:1 · Berean Standard Bible
As a prisoner in the Lord, then, I urge you to walk in a manner worthy of the calling you have received:
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.