Ìṣe àwọn Aposteli 26:1
Acts 26:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Agrippa sì wí fún Paulu pé, “A fún ọ láààyè láti sọ tí ẹnu rẹ.” Nígbà náà ní Paulu ná ọwọ́, ó sì sọ ti ẹnu rẹ pé,
Acts 26:1 in English
Acts 26:1 · Berean Standard Bible
Agrippa said to Paul, “You have permission to speak for yourself.” Then Paul stretched out his hand and began his defense:
Context
1Agrippa sì wí fún Paulu pé, “A fún ọ láààyè láti sọ tí ẹnu rẹ.”
Nígbà náà ní Paulu ná ọwọ́, ó sì sọ ti ẹnu rẹ pé, 2“Agrippa ọba, inú èmi tìkára mi dùn nítorí tí èmi yóò wí ti ẹnu mi lónìí níwájú rẹ, ní ti gbogbo ẹ̀sùn tí àwọn Júù fi kan mi, 3pàápàá bí ìwọ tí mọ gbogbo àṣà àti ọ̀ràn tí ń bẹ́ láàrín àwọn Júù dájúdájú. Nítorí náà, èmi bẹ̀ ọ́ kí ìwọ fi sùúrù tẹ́tí gbọ́ tèmi.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.