Native Bible

2 Samuel 23:37 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Seleki ará Ammoni, Naharai ará Beeroti, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Joabu ọmọ Seruiah;

2 Samuel 23:37 in English

2 Samuel 23:37 · Berean Standard Bible

Zelek the Ammonite, Naharai the Beerothite, the armor-bearer of Joab son of Zeruiah,

Context

35Hesro ará Karmeli, Paarai ará Arba; 36Igali ọmọ Natani ti Soba, Bani ará Gadi; 37Seleki ará Ammoni, Naharai ará Beeroti, ẹni tí ń ru ìhámọ́ra Joabu ọmọ Seruiah; 38Ira ará Itri, Garebu ará Itri. 39Uriah ará Hiti. Gbogbo wọn jẹ́ mẹ́tàdínlógójì.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.