Native Bible

1 Timothy 5:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Má ṣe bá àgbàlagbà ọkùnrin wí, ṣùgbọ́n kí ó máa gbà á níyànjú bí i baba; àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin bí arákùnrin.

1 Timothy 5:1 in English

1 Timothy 5:1 · Berean Standard Bible

Do not rebuke an older man, but appeal to him as to a father. Treat younger men as brothers,

Context

1Má ṣe bá àgbàlagbà ọkùnrin wí, ṣùgbọ́n kí ó máa gbà á níyànjú bí i baba; àwọn ọ̀dọ́mọkùnrin bí arákùnrin. 2Àwọn àgbàlagbà obìnrin bí ìyá; àwọn ọ̀dọ́mọbìnrin bí arábìnrin nínú ìwà mímọ́. 3Bọ̀wọ̀ fún àwọn opó ti í ṣe opó nítòótọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.