Native Bible

1 Kings 6:30 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ó sì tún fi wúrà tẹ́ ilẹ̀ ilé náà nínú àti lóde.

1 Kings 6:30 in English

1 Kings 6:30 · Berean Standard Bible

And he overlaid the temple floor with gold in both the inner and outer sanctuaries.

Context

28Ó sì fi wúrà bo àwọn kérúbù náà. 29Lára àwọn ògiri tí ó yí ilé náà ká, nínú àti lóde, ó sì ya àwòrán àwọn kérúbù sí i àti ti igi ọ̀pẹ, àti ti ìtànná ewéko. 30Ó sì tún fi wúrà tẹ́ ilẹ̀ ilé náà nínú àti lóde. 31Nítorí ojú ọ̀nà ibi mímọ́ jùlọ ni ó ṣe ìlẹ̀kùn igi olifi sí pẹ̀lú àtẹ́rígbà àti òpó ìhà jẹ́ ìdámárùn-ún ògiri. 32Àti lára ìlẹ̀kùn igi olifi náà ni ó ya àwòrán àwọn kérúbù, igi ọ̀pẹ àti ti ìtànná ewéko sí, ó sì fi wúrà bò wọ́n, ó sì tan wúrà sí ara àwọn kérúbù àti sí ara igi ọ̀pẹ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.