1 Kronika 5:2
1 Chronicles 5:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí Juda borí àwọn arákùnrin rẹ̀, àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni aláṣẹ ti ń jáde wá; ṣùgbọ́n ogún ìbí jẹ́ ti Josẹfu),
1 Chronicles 5:2 in English
1 Chronicles 5:2 · Berean Standard Bible
And though Judah prevailed over his brothers and a ruler came from him, the birthright belonged to Joseph.
Context
1Ǹjẹ́ àwọn ọmọ Reubeni, àkọ́bí Israẹli. (Nítorí òun ni àkọ́bí; ṣùgbọ́n, bí ó ti ṣe pé ó ba ibùsùn baba rẹ̀ jẹ́, a fi ogún ìbí rẹ̀ fún àwọn ọmọ Josẹfu ọmọ Israẹli: a kì yóò sì ka ìtàn ìdílé náà gẹ́gẹ́ bí ipò ìbí. 2Nítorí Juda borí àwọn arákùnrin rẹ̀, àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni aláṣẹ ti ń jáde wá; ṣùgbọ́n ogún ìbí jẹ́ ti Josẹfu), 3àwọn ọmọ Reubeni àkọ́bí Israẹli ni:
Hanoku àti Pallu, Hesroni àti Karmi. 4Àwọn ọmọ Joẹli:
Ṣemaiah ọmọ rẹ̀, Gogu ọmọ rẹ̀,
Ṣimei ọmọ rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.