Native Bible

1 Chronicles 12:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Eseri sì jẹ́ ìjòyè, Obadiah sì jẹ́ igbákejì akọgun, Eliabu ẹlẹ́ẹ̀kẹta,

1 Chronicles 12:9 in English

1 Chronicles 12:9 · Berean Standard Bible

Ezer the chief, Obadiah the second in command, Eliab the third,

Context

7àti Joẹla, àti Sebadiah àwọn ọmọ Jerohamu láti Gedori. 8Díẹ̀ lára àwọn ará Gadi yà sọ́dọ̀ Dafidi ní ibi gíga ní aginjù. Wọ́n sì jẹ́ onígboyà ológun tí ó múra fún ogun tí ó sì lágbára láti di asà àti ẹṣin mú. Ojú wọn sì dàbí ojú kìnnìún, wọ́n sì yára bí àgbọ̀nrín lórí àwọn òkè. 9Eseri sì jẹ́ ìjòyè, Obadiah sì jẹ́ igbákejì akọgun, Eliabu ẹlẹ́ẹ̀kẹta, 10Miṣimana ẹlẹ́ẹ̀kẹrin, Jeremiah ẹlẹ́ẹ̀karùnún 11Attai ẹlẹ́ẹ̀kẹfà, Elieli èkeje,

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.